Apa Anglican

Yoruba Hymn APA 600 - Olorun, d’ Oba si

Yoruba Hymn  APA 600 - Olorun, d’ Oba si APA 600  1. Olorun, d’ Oba si,  K’Oba k’o pe titi,  Da Oba si.  Jo, fun ni isegun,  Irora at’ ogo,  K’ o job ape titi,  Da Oba si. 2. Dide, Olorun wa,  T’ awon ota re ka,  Bi won subu.  Mu…

Yoruba Hymn APA 599 - Ogo, ola, at’ agbara

Yoruba Hymn  APA 599 - Ogo, ola, at’ agbara APA 599 Ogo, ola, at’ agbara,  Ni f’ Od’agutan titi;  Jesu l’Olurapada wa,  Halleluya! titi lai.

Yoruba Hymn APA 598 - E korin s’Olorun wa

Yoruba Hymn  APA 598 - E korin s’Olorun wa APA 598  E korin s’Olorun wa,  E ma yin titi lailai;  Yin, enyin ogun orun,  Baba, Omo, on Emi.

Yoruba Hymn APA 597 - Iyin, ola, ogo, ’bukun

Yoruba Hymn  APA 597 - Iyin, ola, ogo, ’bukun APA 597  Iyin, ola, ogo, ’bukun,  L’awa nfi f’oruko Re:  T’agba t’ ewe jumo korin,  Lati yin Olugbala;  B’awon mimo l’orun ti nyin,  A wole niwaju Re;  B’ Angel ti nsin niwaju Re,  Be…

Yoruba Hymn APA 596 - Orun ododo, jowo la

Yoruba Hymn  APA 596 - Orun ododo, jowo la APA 596  1. Orun ododo, jowo la,  Ma ran jeje lori Sion,  Tu okunkun oju wa ka,  Je k’okan wa k’o ji si ’ye. 2. Je k’ore-ofe ba le wa,  B’iri orun, b’opo ojo:  K’ a le mo p’On l’Ore wa s…

Yoruba Hymn APA 595 - F’ awon Ijo ti nsimi

Yoruba Hymn  APA 595 - F’ awon Ijo ti nsimi APA 595  1. F’ awon Ijo ti nsimi, Awa Ijo t’ aiye; A f’ iyin gbogbo fun O, Jesu Olubukun; Oluwa, O ti segun, Ki nwon ba le segun; ’Mole ade ogo won, Lat’ odo Re wa ni. St. Anderu. A yin…

Yoruba Hymn APA 594 - E tun won ko fun mi ki ngbo

Yoruba Hymn  APA 594 - E tun won ko fun mi ki ngbo APA 594 1. E tun won ko fun mi ki ngbo,  Oro ’yanu t’ Iye!  Je ki nsi tun ewa won ri,  Oro ’yanu t’ Iye!  Oro iye at’ ewa, ti nko mi n’ igbagbo!  Oro didun ! Oro ’yanu!  Oro ’ya…

Yoruba Hymn APA 593 - Ore-ofe! ohun

Yoruba Hymn  APA 593 - Ore-ofe! ohun APA 593 1. Ore-ofe! ohun  Adun ni l’ eti wa:  Gbohun-gbohun re y’o gba orun kan,  Aiye o gbo pelu.  Ore-ofe sa,  N’ igbekele mi;  Jesu ku fun araiye,  O ku fun mi pelu. 2. Ore-ofe lo ko  Oruk…

Yoruba Hymn APA 592 - Enyin ’ranse Kristi

Yoruba Hymn  APA 592 - Enyin ’ranse Kristi APA 592 1. Enyin ’ranse Kristi,  Gbo ohun ipe Re;  E tele ’bi t’ o fonahan,  A npe nyin s’ ona Re. 2. Baba ti enyin nsin,  O n’ ipa to fun nyin;  N’ igbekele ileri Re,  E ja bi okunrin. …

Yoruba Hymn APA 591 - Oluwa, emi sa ti gbohun Re

Yoruba Hymn  APA 591 - Oluwa, emi sa ti gbohun Re APA 591  1. Oluwa, emi sa ti gbohun Re,  O nso ife Re si mi:  Sugbon mo fen de l’apa igbagbo,  Kin le tubo sunmo O.  Fa mi mora, mora Oluwa,  Sib’ agbelebu t’O ku,  Fa mi mora, mo…

Yoruba Hymn APA 590 - Wo oro t’o dun julo

Yoruba Hymn  APA 590 - Wo oro t’o dun julo APA 590 1. ’Wo oro t’o dun julo,  Ninu eyit’ a ri  Ileri at’ imuse  Awamaridi ni:  Nigba ekun at’ ayo,  ’Yemeji at’ eru,  Mo gbo Jesu wipe, “Wa,”  Mo si lo sodo Re.  Wa, wa sodo Mi,  Wa…

Yoruba Hymn APA 589 - Wo bi awa enia Re

Yoruba Hymn  APA 589 - Wo bi awa enia Re APA 589  1. Wo bi awa enia Re  Ti wole l’ ese Re;  Olorun ! kiki anu Re  Ni igbekele wa. 2. Idajo t’o ba ni leru,  Nfi agbara Re han;  Sibe, anu da ’lu wa si,  Awa si ngbadura. 3. Olorun, …

Yoruba Hymn APA 588 - Gb’ adura wa, Oba aiye

Yoruba Hymn  APA 588 - Gb’ adura wa, Oba aiye APA 588  1. Gb’ adura wa, Oba aiye,  ’Gbat’ a wole fun O;  Gbogbo wa nkigbe n’ irele,  A mbebe fun anu.  Tiwa l’ ebi, Tire l’ anu,  Mase le wa pada;  Sugbon gbo ’gbe wa n’ite Re,  Ran…

Yoruba Hymn APA 587 - Olugbala gbohun mi

Yoruba Hymn  APA 587 - Olugbala gbohun mi APA 587 1. Olugbala gbohun mi, Gbohun mi, gbohun mi; Mo wa sodo Re, gba mi, Nibi agbelebu. Emi se, sugbon, O ku; Iwo ku, Iwo ku; Fi anu Re pa mi mo. Nibi agbelebu. Oluwa, jo gba m…

Yoruba Hymn APA 586 - Ma koja mi, Olugbala

Yoruba Hymn  APA 586 - Ma koja mi, Olugbala APA 586  1. Ma koja mi, Olugbala,  Gbo adura mi;  ’Gbat’ Iwo ba np’ elomiran,  Mase koja mi!  Jesu! Jesu! Gbo adura mi!  Gbat’ Iwo ba np’ elomiran,  Mase koja mi. 2. N’ ite-anu, je k’ e…

Yoruba Hymn APA 585 - Jesu, o ha le je be pe

Yoruba Hymn  APA 585 - Jesu, o ha le je be pe APA 585 1. Jesu, o ha le je be pe,  Ki eni kiku tiju Re?  Tiju Re!-Wo t’ Angeli nyin,  Ogo Eni nran titi lai! 2. Ki ntiju Jesu! O ya se  Ki ale tiju irawo:  On ni ntan imole orun  Si…

Yoruba Hymn APA 584 - Enit’ O la ’ju afoju

Yoruba Hymn  APA 584 - Enit’ O la ’ju afoju APA 584 1. Enit’ O la ’ju afoju,  Ti O mu ope gbon,  At’ enit’ O da imole,  Fun eni okunkun. 2. Enit’ O le fi agbara  F’ awon olokunrun,  Ti O si fie mi iye  Fun awon t’o ti ku. 3. Eni…

Yoruba Hymn APA 583 - Otosi elese ni mi

Yoruba Hymn  APA 583 - Otosi elese ni mi APA 583 1. Otosi elese ni mi,  Mo l’ore Alagbara kan,  Olugbala l’oruko Re;  Ife Tire ko nipekun. 2. O ri mo sina kakiri,  O mu mi wo agbo Re wa,  O fie je mimo ra mi,  O si segun ota fun…

Yoruba Hymn APA 582 - Igba aro ati ayo

Yoruba Hymn  APA 582 - Igba aro ati ayo APA 582 1. Igba aro ati ayo  Lowo Re ni o wa,  Itunu mi t’owo Re wa,  O si lo l’ase Re. 2. Bi O fe gba won lowo mi,  Emi ki o binu;  Ki emi ki o to ni won,  Tire ni nwon ti se. 3. Emi ki y…

Yoruba Hymn APA 581 - Awa fe ohun aiye yi

Yoruba Hymn  APA 581 - Awa fe ohun aiye yi APA 581 1. Awa fe ohun aiye yi,  Nwon dara l’ oju wa;  A fe k’a duro pe titi,  Laifi won sile lo. 2. Nitori kini a nse be?  Aiye kan wa loke;  Nibe l’ ese on buburu  Ati ewu ko si. 3. A…

Load More
That is All