Yoruba Hymn APA 162 - O su mi lati ma sako

Yoruba Hymn APA 162 - O su mi lati ma sako

 Yoruba Hymn  APA 162 - O su mi lati ma sako

APA 162

1. O su mi lati ma sako,

 O to ge, ngo wa Olorun;

 Mo teriba fun opa Re:

 Fun O mo ns’ofo n’nu ’reti:

 Mo n’ Alagbawi kan loke,

 Ore niwaju ’te ife.


2. A ! Jesu t’ o kun f’or’ofe

 Ju bi mo ti kun fun ese,

 Lekan si mo tun nw’oju Re,

 N’ apa Re, si gba mi mora;

 L’ofe wo ’fasehin mi san,

 Fe em’ alaigbagbo sibe.


3. ’Wo m’ona lati pe mi bo,

 Lati gb’emi t’o subu ro;

 A ! ’tor’anu at’oto Re,

 Dariji, ma je ki m’se mo;

 Tun ibaje okan mi se,

 K’o si se n’ile adura.


4. A ! fun mi ni okan riro,

 Ti y’o ma wariri f’ese;

 Fun mi ni iberu f’ese,

 Mu k’o ta gbongbo ninu mi;

 Kin le beru agbara Re,

 Kin ma tun je se si O mo. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 162- O su mi lati ma sako . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post