Apa

Yoruba Anglican Hymn Apa 20 - Wo Imole! larin okun aiye

Yoruba Hymn Apa 20 - Wo Imole! larin okun aiye APA 20  1. ’Wo Imole ! larin okun aiye,  Ma sin mi lo.  Okunkun su, mo si jina s’ ile;  Ma sin mi lo.  To ’sise mi: ohun ehin ola  Emi ko bere; ’sise kan to fun mi.   2. Nigbakan ri,…

Yoruba Anglican Hymn Apa 19 - Ero di| dun kan| nso

Yoruba Hymn Apa 19 - Ero di| dun kan| nso APA 14  1. Ero di| dun kan|  nso  S’okan | mi fi|  rifi| ri-  Mo sunmo ’le |  mi lo | ni,  Ju bi | mo ti | sunmo | ri. 2. Mo sunmo | ’te nla | ni,  Mo sunm’ | okun | Krista li,  Mo sunmo …

Yoruba Anglican Hymn Apa 18 - Baba, a tun pade l’oko Jesu

Yoruba Hymn Apa 18 - Baba, a tun pade l’oko Jesu APA 18  1. Baba, a tun pade l’oko Jesu,  A si wa teriba lab’ ese Re:  A tun fe gb’ ohun wa soke si O  Lati wa anu, lati korin ’yin.   2. A yin O fun itoju ’gbagbogbo,  Ojojumo l’ a…

Yoruba Anglican Hymn Apa 17 - L’ oju ale, ’gbat ’orun wo

Yoruba Hymn Apa 17 - L’ oju ale, ’gbat ’orun wo APA 14  1. L’ oju ale, ’gbat ’orun wo,  N won gbe abirun w’ odo Re:  Oniruru ni aisan won,  Sugbon nwon f’ ayo lo ’le won. 2. Jesu a de l’ oj’ ale yi,  A sunmo, t’ awa t’ arun wa, …

Yoruba Anglican Hymn Apa 16 - Iwo Imole okan mi

Yoruba Hymn Apa 16 - Iwo Imole okan mi APA 14  1. Iwo Imole okan mi,  Li odo Re oru ko si,  Ki kuku aiye ma bo O,  Kuro l’ oju iranse Re.   2. Nigbat’ orun ale didun  Ba npa ipenpeju mi de,  K’ ero mi je lati simi  Lai laiya Olu…

Yoruba Anglican Hymn Apa 15 - Wa ba mi gbe! ale fere le tan

Yoruba Hymn Apa 15 - Wa ba mi gbe! ale fere le tan APA 15 1. Wa ba mi gbe ! ale fere le tan,  Okunkun nsu; Oluwa ba mi gbe,  Bi oluranlowo miran ba ye,  Iranwo alaini, wa ba mi gbe ! 2. Ojo aiye mi nsare lo s’opin,  Ayo aiye nku,…

Yoruba Anglican Hymn apa 10 - Baba mi gbo temi

Yoruba Hymn Apa 10 - Baba mi gbo temi APA 10 1. Baba mi gbo temi !  ’Wo ni alabo mi,  Ma sunmo mi titi:  Oninure julo !   2. Jesu Oluwa mi,  Iye at’ ogo mi,  K’ igba na yara de,  Ti ngo de odo Re. 3. Olutunu julo,  ’Wo ti ngbe in…

Yoruba Anglican Hymn APA 9 - Jesu, Orun ododo

Yoruba Hymn APA 9 - Jesu, Orun ododo APA 9 1. Jesu, Orun ododo,  Iwo imolfe ife;  Gbat’ imole owuro  Ba nt’ ila orun tan wa,  Tanmole ododo Re  Yi wa ka.  2. Gege bi iri tin se  Sori eweko gbogbo,  K’ Emi ore-ofe Re  So okan wa d…

Yoruba Anglican Hymn APA 8- Imole oro, didun yi

Yoruba Hymn APA 8 - Imole oro, didun yi APA 8  1. Imole oro, didun yi  Ji mi nin’ orun mi;  Baba, ife Tire nikan  L’ o pa omo Re mo. 2. Ni gbogbo oni, mo be O,  Ma se Oluso mi;  Dariji mi, Jesu mimo  Ki’ m je Tire loni.   3. Wa s…

Yoruba Anglican Hymn APA 3 - Nigbat’ imole owuro

Yoruba Hymn APA 3 - Nigbat’ imole owuro APA 3 1. Nigbat’ imole owuro  B anti ila orun tan wa,  A! Orun ododo mimo  Ma sai fi anu ran si mi !  Tu isudede ebi ka  S’ okunkun mi d’ imole nla. 2. ’Gbati mba m’ ebo oro wa  ’Waju Oloru…

Yoruba Anglican Hymn APA 4 - Oluwa mi, mo njade lo

Yoruba Hymn APA  4 - Oluwa mi, mo njade lo APA 4  1. Oluwa mi, mo njade lo,  Lati se ise ojo mi;  Iwo nikanl’ emi o mo,  L’ oro, l’ ero, ati n’ ise.   2. Ise t’ o yan mi, l’ anu Re,  Je ki nle se tayotayo;  Ki nr’ oju Re ni ise …

Yoruba Anglican Hymn Apa 5 - Wa s’odo mi, Oluwa mi

Yoruba Hymn Apa 5 - Wa s’odo mi, Oluwa mi APA 5 1. Wa s’odo mi, Oluwa mi,  Ni kutukutu owuro;  Mu k’ ero rere so jade,  Lat’ inu mi soke orun. 2. Wa s’odo mi Oluwa mi,  Ni wakati osan gangan;  Ki ’yonu ma ba se mi mo  Nwon a si s…

Yoruba Anglican Hymn APA 6 - Krist, Ologo, Olola

Yoruba Hymn Apa 6 - Krist, Ologo, Olola APA 6 1. Krist, Ologo, Olola, Iwo imole aiye, Orun ododo, dide, K’ o si bori okunkun; ‘Mole oro, sunmo mi, ‘Rawo oro, w’aiya mi. 2. Okunkun l’owuro je B’ Iwo ko pelu re wa; Ailayo l’ojo yi …

Yoruba Anglican Hymn Apa 7 - Wa s’ adura oro

Yoruba Hymn APA 7 - Wa s’ adura oro APA 7  1. Wa s’ adura oro,  Kunle k’ a gbadura;  Adura ni opa Kristian,  Lati b’ Olorun rin.   2. Losan, wole labe  Apat’ aiyeraiye;  Itura ojiji Re dun  Nigbat’ orun ba mu. 3. Je ki gbogbo ile…

Yoruba Hymn APA 486 - Oj’ oni lo

Yoruba Hymn  APA 486 - Oj’ oni lo APA 486  1. Oj’ oni lo,  Jesu Baba,  Boju Re w’ emi omo Re. 2. ’Wo Imole,  Se ’toju mi;  Tan imole Re yi mi ka. 3. Olugbala,  Nko ni beru,  Nitori O wa lodo mi. 4. Nigba gbogbo  Ni oju Re  Nso mi…

Yoruba Hymn APA 187 - Mokandilogorun dubule je

Yoruba Hymn  APA 187 - Mokandilogorun dubule je APA 187  1. Mokandilogorun dubule je  Labe oji nin’ agbo;  Sugbon okan je lo or’ oke,  Jina s’ ilekun wura :  Jina rere lor’ oke sisa,  Jina rere s’ Olusagutan. 2. “Mokandilogorunn …

Yoruba Hymn APA 181 - Olorun ’yanu ! ona kan

Yoruba Hymn  APA 181 - Olorun ’yanu ! ona kan APA 181  1. Olorun ’yanu ! ona kan  Ti o dabi Tire ko si:  Gbogb’ ogo ore-ofe Re,  L’ o farahan bi Olorun.  Tal’ Olorun ti ndariji,  Ore tal’ o po bi Tire ? 2. N’ iyanu at’ ayo l’ a g…

Yoruba Hymn APA 180 - Mo f’ igbagbo b’ Olorun rin

Yoruba Hymn  APA 180 - Mo f’ igbagbo b’ Olorun rin APA 180 1. Mo f’ igbagbo b’ Olorun rin,  Orun ni opin ajo mi;  “Op’ at’ ogo Re tu mi n’nu,”  Ona didun l’ ona t’ o la. 2. Mo nrin l’ arin aginju nla,  Nibi opolopo ti nu;  Sugbo…

Yoruba Hymn APA 179 - Baba alanu t’o fe wa

Yoruba Hymn  APA 179 - Baba alanu t’o fe wa APA 179 1. Baba alanu t’o fe wa,  Mo gb’ okan mi si O;  Ipa Re t’ o po l’ o gba wa;  Awa nkorin si O. 2. Tire papa l’ awa fe se,  Gb’ okan wa fun ebo;  O da wa, o sit un wa bi,  A f’ a…

Yoruba Hymn APA 178 - F’ ore-ofe Re ba wa gbe

Yoruba Hymn  APA 178 -  F’ ore-ofe Re ba wa gbe APA 178  1. F’ ore-ofe Re ba wa gbe,  Jesu Olugbala;  Ki eni arekereke,  K’ o ma le kolu wa. 2. F’ oro mimo Re ba wa gbe,  Jesu iyebiye;  K’ a ri igbala on iye,  Lohun, bi nihinyi. …

Load More
That is All