Yoruba Hymn APA 180 - Mo f’ igbagbo b’ Olorun rin

Yoruba Hymn APA 180 - Mo f’ igbagbo b’ Olorun rin

 Yoruba Hymn  APA 180 - Mo f’ igbagbo b’ Olorun rin

APA 180

1. Mo f’ igbagbo b’ Olorun rin,

 Orun ni opin ajo mi;

 “Op’ at’ ogo Re tu mi n’nu,”

 Ona didun l’ ona t’ o la.


2. Mo nrin l’ arin aginju nla,

 Nibi opolopo ti nu;

 Sugbon on t’ o samona wa,

 Ko je ki nsina, ti mba nu.


3. Mo nla ’kekun t’ on ewu ja,

 Aiye at’ Esu kolu mi;

 Agbara Re ni mo fi la,

 Igbagbo si ni ’segun mi.


4. Mo nkanu awon ti nhale,

 F’afe aiye ti nkoja yi:

 Oluwa je ki mba O rin,

 Olugbala at’ Ore mi. Amin.

 Yoruba Hymn  APA 180 - Mo f’ igbagbo b’ Olorun rin


This is Yoruba Anglican hymns, APA 180- Mo f’ igbagbo b’ Olorun rin . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post