Yoruba Hymn APA 205 - Olorun fe araiye

Yoruba Hymn APA 205 - Olorun fe araiye

Yoruba Hymn  APA 205 - Olorun fe araiye

APA 205

 1. Olorun fe araiye,

 O fe tobe ge;

 T’ o ran omo Re w’ aiye,

 T’ o ku fun elese;

 Olorun ti mo tele

 Pe, emi o se si

 Ofin, ati ife Re,

 Iwo ha fe mi bi?


2. Loto Olorun fe mi,

 Ani-ani ko si;

 Awon t’ o yipada si,

 Igbala ni nwon ri.

 Wo! Jesu Kristi jiya,

 Igi l’ a kan a mo:

 Wo! eje Re ti o san,

 Wo! ro! ma dese mo.


3. Jesu, agbelebu Re ni

 Ngo kan ese mi mo;

 Labe agbelebu Re,

 Ngo we ese mi nu.

 Nigbat’ emi o ri O,

 Ni orun rere Re;

 Nki yio dekun yin O,

 F’ ogo at’ ola Re. Amin.Yoruba Hymn  APA 205 - Olorun fe araiye

This is Yoruba Anglican hymns, APA 205 -  Olorun fe araiye . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post