Yoruba Hymn APA 210 - Enyin ti nkoja

Yoruba Hymn APA 210 - Enyin ti nkoja

 Yoruba Hymn  APA 210 - Enyin ti nkoja

APA 210

1. Enyin ti nkoja,

 Ya sodo Jesu:

O s’asan fun nyin bi, pe ki Jesu ku?


2. Alafia nyin:

 Onigbowo nyin:

Wa wo bi banuje kan ri bayi ri.


3. Oluwa n’ jo na,

 N’ ibinu Re gbe

Ese nyin l’ Odagutan, O ko won lo.


4. O ku, k’ o s’ etu

 Nitor’ ese nyin:

Baba se Omo Re n’ ise ’tori nyin.


5. K’ a gb’ ore-ofe

 Irapada mu,

Fun eni t’ o jiya t’o ku nipo wa.


6. Nigb’ aiye ba pin

 Awa o ma bo

Ife titobi na, ti ki tan lailai. Amin.Yoruba Hymn  APA 210 - Enyin ti nkoja

This is Yoruba Anglican hymns, APA 210-  Enyin ti nkoja  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post