Yoruba Hymn APA 216 - Simi okan mi, ni ireti

Yoruba Hymn APA 216 - Simi okan mi, ni ireti

 Yoruba Hymn  APA 216 - Simi okan mi, ni ireti

APA 216

1. Simi okan mi, ni ireti;

 Ma beru bi ola ti le ri,

 Sa simi, iku papa l’ ona;

 Iranse Oba t’a ran si o.


2. Simi okan mi, Jesu ti ku,

 Loto o si ti jinde pelu;

 Eyi to fun ireti mi, pe

 Mo ku, mo si ye, ninu Jesu.


3. Simi okan mi, “O ti pari;”

 Jesu pari ’se igbala Re;

 Simi, a ti se gbogbo re tan

 Lekan lai; igbala di tire.


4. Ogo fun Jesu ti O jinde!

 ’Wo t’a bi, t’a pa fun araiye:

 Ogo fun Metalokan lailai!

 Fun Baba, Omo, ati Emi. Amin.Yoruba Hymn  APA 216 - Simi okan mi, ni ireti

This is Yoruba Anglican hymns, APA 216-  Simi okan mi, ni ireti  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post