Yoruba Hymn APA 350 - Oluwa, Iwo ha wipe

Yoruba Hymn APA 350 - Oluwa, Iwo ha wipe

Yoruba Hymn  APA 350 -  Oluwa, Iwo ha wipe

APA 350

 1. Oluwa, Iwo ha wipe,

 Ki mbere ohun ti mo nfe?

 Jo, je ki mbo lowo ebi,

 Ati low’ese on Esu.


2. Jo, fi ara Re han fun mi,

 Si je ki nru aworan Re,

 Te ite Re si okan mi,

 Si ma nikan joba nibe.


3. Je kin mo p’O dariji mi,

 Ki ayo Re s’agbara mi;

 Kin mo giga, ibu, jijin

 Ati gigun ife nla Re.


4. Eyi nikan ni ebe mi,

 Eyit’ o ku di owo Re;

 Iye, iku, aini, oro,

 Ko je nkan, b’O ba je temi. Amin.Yoruba Hymn  APA 350 -  Oluwa, Iwo ha wipe

This is Yoruba Anglican hymns, APA 350-  Oluwa, Iwo ha wipe. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post