Yoruba Hymn APA 363 - Olorun emi wa, at’ igbala wa

Yoruba Hymn APA 363 - Olorun emi wa, at’ igbala wa

Yoruba Hymn  APA 363 - Olorun emi wa, at’ igbala wa

APA 363

 1. Olorun emi wa, at’ igbala wa,

 ’Mole okunkun wa, ’reti ile wa,

 Gbo, ki O si gba ebe Ijo Re yi,

 Olodumare.


2. Wo bi ibinu ti yi Arki Re ka,

 Wo b’ awon ota Re ti nt’ asia won,

 Bi nwon si ti nju oko oloro won,

 ’Wo le pa wa mo.


3. ’Wo le seranwo, b’ iranwo aiye ye,

 ’Wo le gba ni la b’oku ese gbija;

 Iku at’ Esu ko le bor’ Ijo Re;

 F’ alafia fun wa.


4. Ran wa lowo tit’ ota o pehinda,

 Fun won l’oto Re, ki a le dariji won,

 K’a r’ alafia laiye, lehin ija wa,

 Alafia l’orun. Amin.Yoruba Hymn  APA 363 - Olorun emi wa, at’ igbala wa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 363- Olorun emi wa, at’ igbala wa  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post