Yoruba Hymn APA 365 - Ngo se foiya ojo ibi

Yoruba Hymn APA 365 - Ngo se foiya ojo ibi

Yoruba Hymn  APA 365 - Ngo se foiya ojo ibi 

APA 365

1. Ngo se foiya ojo ibi?

 Tabi kin ma beru ota?

 Jesu papa ni odi mi.


2. B’o ti wu k’ ija gbona to!

 K’a mase gbo pee mi nsa;

 ’Tori Jesu l’ apata mi.


3. Nko mo ’hun t’o le de, nko mo

 Bi nki y’o ti se wa l’aini;

 Jesu l’o mo, y’o si pese.


4. Bi mo kun f’ ese at’ osi,

 Mo le sunmo Ite-anu;

 ’Tori Jesu l’ ododo mi.


5. B’ adura mi ko ni lari,

 Sibe ’reti mi ki o ye;

 ’Tori Jesu mbebe loke.


6. Aiye at’ esu nde si mi;

 Sugbon Olorun wa fun mi;

 Jesu l’ohun gbogbo fun mi. Amin.Yoruba Hymn  APA 365 - Ngo se foiya ojo ibi 

This is Yoruba Anglican hymns, APA 365- Ngo se foiya ojo ibi  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post