Yoruba Hymn APA 469 - Orun tanmole

Yoruba Hymn APA 469 - Orun tanmole

Yoruba Hymn  APA 469 - Orun tanmole

APA 469

 1. Orun tanmole;

Oru ti sa lo;

Gbogbo ’ro ayo l’o ndun kakiri.


2. Oro dun mo mi,

Ope f’ Olorun:

Oluso tin so mi nigba mo sun.


3. Gbo, ’gba mo ba nde,

Ori ’yin mi yi

K’ okan mi k’o ba o duro loni. Amin.Yoruba Hymn  APA 469 - Orun tanmole

This is Yoruba Anglican hymns, APA 469-  Orun tanmole . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post