Yoruba Hymn APA 481 - Gba Jesu f’ ite Re sile

Yoruba Hymn APA 481 - Gba Jesu f’ ite Re sile

Yoruba Hymn  APA 481 - Gba Jesu f’ ite Re sile

APA 481

 1. ’Gba Jesu f’ ite Re sile,

 O mu ’po irele;

 Ni ’rele o mu awo wa,

 O wa gbe ’nu aiye.


2. A ba le rin bi On ti rin,

 Nipa ona ogbon;

 K’ a dagba l’ ore at’ ogbon,

 Bi odun ti npo si.


3. Didun l’ oro, at’ iwo Re;

 Gb’ awon iya sunmo;

 O gbe omo won s’ apa Re,

 O si sure fun wom.


4. Labe itoju Re, nwon bo

 Lowo ’tanje aiye:

 Bayi ni k’ awa dubule,

 Ni iso oju Re.


5. ’Gba Jesu gun ketekete,

 Awon ’mode nkorin;

 L’ ayo nwon ke eka igi,

 Nwon si te ’so sile.


6. B’ awa gbagbe iyin Jesu,

 Okuta y’o korin!

 Hosanna ni awa o ko,

 Hosanna s’ Oba wa. Amin.Yoruba Hymn  APA 481 - Gba Jesu f’ ite Re sile

This is Yoruba Anglican hymns, APA 481- Gba Jesu f’ ite Re sile . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post