Yoruba Hymn APA 143 - Oluwa, ma moju kuro

Yoruba Hymn APA 143 - Oluwa, ma moju kuro

 Yoruba Hymn  APA 143 - Oluwa, ma moju kuro

APA 143

1. Oluwa, ma moju kuro

 L’ odo emi t’ o nyile;

 Ti nsokun ese aiye mi,

 N’ ite anu ife Re.


2. Ma ba mi lo sinu ’dajo,

 Bi ese mi tip o to;

 Nitori mo mo daju pe,

 Emi ko wa lailebi.


3. Iwo mo, ki nto jewo re,

 Bi mo tin se laiye mi;

 At’ iwa isisiyi mi,

 Gbogbo re l’o kiyesi.


4. Emi ko ni f’ atunwi se,

 Ohun ti mo fe toro

 Ni iwo mo ki nto bere,

 Anu ni lopolopo.


5. Anu Oluwa ni mo fe;

 Eyi l’opin gbogbo re:

 Tori anu ni mo ntoro,

 Jeki nri anu gba. Amin. 

This is Yoruba Anglican hymns, APA 143 -  Oluwa, ma moju kuro . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post