Yoruba Hymn APA 159 - Oluwa, gbo aroye mi

Yoruba Hymn APA 159 - Oluwa, gbo aroye mi

 Yoruba Hymn  APA 159 - Oluwa, gbo aroye mi

APA 159

1. Oluwa, gbo aroye mi,

 Gbo adura ikoko mi;

 Lodo Re nikan, Oba mi,

 L’ emi o ma wa iranwo.


2. L’ oro Iwo o gbohun mi;

 L’ afemojumo ojo na;

 Ni odo Re l’ emi o wo,

 Si O l’ emi o gbadura.


3. Sugbon nigb’ ore-ofe Re

 Ba mu mi de agbala Re,

 Odo Re l’ em’ o teju mo,

 Nibe ngo sin O n’ irele.


4. Je k’ awon t’ o gbekele O,

 L’ ohun rara wi ayo won:

 Je k’ awon t’ Iwo pamo yo,

 Awon t’ o fe oruko Re.


5. Si olododo l’ Oluwa

 O na owo ibukun Re;

 Ojurere Re l’ enia Re

 Yio si fi se asa won. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 159 - Oluwa, gbo aroye mi . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post