Yoruba Hymn APA 160 - Baba ma yi oju kuro

Yoruba Hymn APA 160 - Baba ma yi oju kuro

Yoruba Hymn  APA 160 - Baba ma yi oju kuro

APA 160

 1. Baba ma yi oju kuro,

 Fun emi otosi;

 Ti npohunrere ese mi

 N’ iwaju ite Re.


2. ’Lekun anu t’ o si sile,

 F’ akerora ese,

 Mase ti mo mi Oluwa

 Je ki emi wole.


3. Emi ko nip e mo njewo

 B’ aiye mi ti ri ri;

 Gbogbo re l’at’ ehinwa, ni

 ’Wo mo dajudaju.


4. Mo wa si ’lekun anu Re,

 Nibiti anu po:

 Mo fe ’dariji ese mi,

 K’ o mu okan mi da.


5. Emi ko ni ma tenumo

 Itunu ti mo nfe:

 ’Wo mo, Baba, ki’m to bere,

 Ibukun t’emi nwa.


6. Anu, Oluwa, ni mo fe

 Eyiyi l’ opin na;

 Oluwa, anu l’ o ye mi,

 Je ki anu Re wa. Amin.

Yoruba Hymn  APA 160 - Baba ma yi oju kuro

This is Yoruba Anglican hymns, APA 160-  Baba ma yi oju kuro . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post