Yoruba Hymn APA 164 - Wo t’ o ku ni Kalfari

Yoruba Hymn APA 164 - Wo t’ o ku ni Kalfari

Yoruba Hymn  APA 164 -  Wo t’ o ku ni Kalfari

APA 164

1. ’Wo t’ o ku ni Kalfari,

 ’Wo t’ o mbebe f’ elese,

 Ran mi lowo nigb’ aini;

 Jesu, gbo ’gbe mi.


2. Ninu ibanuje mi,

 At’ okan aigbagbo mi,

 Em’ olori elese

 Gb’ oju mi si O.


3. Ota lode, eru n’nu,

 Ko s’ ire kan lowo mi,

 Iwo l’ o ngb’ elese la,

 Mo sa to O wa.


4. Awon miran dese pe,

 Nwon si ri igbala gba,

 Nwon gbo ohun anu Re,

 Mu mi gbo pelu.


5. Mo k’ aniyan mi le O,

 Mo si ngbadua si O,

 Jesu, yo mi n’nu egbe,

 Gba mi, ki mma ku.


6. ’Gbati wahala ba de,

 Nigb’ agbara idanwo,

 Ati lojo ikehin,

 Jesu, sunmo mi. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns,APA 164-  Wo t’ o ku ni Kalfari  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post