Yoruba Hymn APA 165 - Si pepe Oluwa

Yoruba Hymn APA 165 - Si pepe Oluwa

 Yoruba Hymn  APA 165 -  Si pepe Oluwa

APA 165

1. Si pepe Oluwa,

 Mo mu ’banuje wa;

 ’Wo ki o f’ anu tewogba

 Ohun alaiye yi ?


2. Kristi Odagutan

 Ni igbagbo mi nwo:

 ’Wo le ko ’hun alaiye yi ?

 ’Wo o gba ebo mi.


3. ’Gbati Jesu mi ku,

 A te ofin l’ orun;

 Ofin ko ba mi l’ eru mo

 ’Tori pe Jesu ku. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 165-  Si pepe Oluwa . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post