Yoruba Hymn APA 168 - Jesu oluf’ okan mi

Yoruba Hymn APA 168 - Jesu oluf’ okan mi

 Yoruba Hymn  APA 168 - Jesu oluf’ okan mi

APA 168

1. Jesu oluf’ okan mi,

 Je ki nsala s’ aiya Re,

 Sa t’ irumi sunmo mi,

 Sa ti iji nfe s’ oke;

 Pa mi mo Olugbala,

 Tit’ iji aiye y’o pin,

 To mi lo s’ ebute Re,

 Nikehin gba okan mi.


2. Abo mi, emi ko ni,

 Iwo l’ okan mi ro mo;

 Ma f’ emi nikan sile,

 Gba mi, si tu mi ninu.

 Iwo ni mo gbekele,

 Iwo n’ iranlowo mi;

 Ma sai f’ iye apa Re

 D’ abob’ ori aibo mi.


3. Kristi ’Wo nikan ni mo fe,

 N’nu Re, mo r’ ohun gbogbo;

 Gb’ eni t’ o subu dide,

 W’ alaisan, to afoju;

 Ododo l’ oruko Re,

 Alaisododo l’ emi,

 Mo kun fun ese pupo,

 Iwo kun fun ododo.


4. ’Wo l’ opo ore-ofe

 Lati fib o ese mi;

 Je ki omi iwosan

 We inu okan mi mo;

 Iwo l’ orisun iye,

 Je ki mbu n’nu Re l’ ofe;

 Ru jade n’nu okan mi,

 Si iye ainipekun. Amin.

Yoruba Hymn  APA 168 - Jesu oluf’ okan mi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 168-  Jesu oluf’ okan mi  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post