Yoruba Hymn APA 169 - Apata aiyeraiye

Yoruba Hymn APA 169 - Apata aiyeraiye

 Yoruba Hymn  APA 169 -  Apata aiyeraiye

APA 169

1. Apata aiyeraiye,

 Se ibi isadi mi;

 Je ki omi on eje

 T’ o san lati iha Re,

 Se iwosan f’ ese mi,

 K’ o si so mi di mimo.


2. K’ ise ise owo mi

 L’ o le mu ofin Re se;

 B’ itara mi ko l’ are,

 T’ omije mi nsan titi;

 Nwon ko to fun etutu,

 ‘Wo nikan l’ o le gbala.


3. Ko s’ ohun it mo mu wa,

 Mo ro mo agbelebu;

 Mo wa, k’ o d’ as obo mi,

 Mo nwo O fun iranwo;

 Mo wa sib’ orison ni,

 We mi, Olugbala mi.


4. ‘Gbati emi mi ban lo,

 T’ iku ba p’ oju mi de,

 Ti mab nlo s’ aiye aimo,

 Ti nri O n’ ite dajo;

 Apapta aiyeraiye,

 Se ibi isadi mi. Amin.

Yoruba Hymn  APA 169 -  Apata aiyeraiye

This is Yoruba Anglican hymns, APA 169-  Apata aiyeraiye. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post