Yoruba Hymn APA 177 - Jesu, emi o fi okan mi fun O

Yoruba Hymn APA 177 - Jesu, emi o fi okan mi fun O

Yoruba Hymn  APA 177 - Jesu, emi o fi okan mi fun O

APA 177

 1. Jesu, emi o fi okan mi fun O;

 Mo jebi, mo gbe, sugbon ’Wo le gba mi.

 L’aiye ati l’orun, ko s’eni bi re:

 Iwo ku f’elese, f’emi na pelu.


2. Jesu, mo le simi le oruko Re,

 Ti angeli wa so, l’ojo ibi Re;

 ’Yi t’a ko, ti o han l’or’ agbelebu,

 Ti elese si ka; nwon si teriba.


3. Jesu, emi ko le sai gbekele O,

 Ise Re l’ aiye, kun f’anu, at’ ife:

 Elese yi O ka, adete ri O,

 Ko s’eni buruju, ti ’Wo ko le gba.


4. Jesu, mo le gbeke mi le oro Re,

 Bi nko tile gb’ ohun anu Re ri;

 Gbat’ Emi Re nkoni, o ti dun po to,

 Ki nsa fi ’barale, k’eko l’ese Re.


5. Jesu, toto-toto, mo gbekele O:

 Enikeni t’o wa, ’Wo ki o tanu;

 Oto ni ’leri Re, owon l’eje Re;

 Wonyi ni ’gbala mi, ’Wo l’Olorun mi. Amin.

Yoruba Hymn  APA 177 - Jesu, emi o fi okan mi fun O

This is Yoruba Anglican hymns, APA 177-   Jesu, emi o fi okan mi fun O . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post