Yoruba Hymn APA 178 - F’ ore-ofe Re ba wa gbe

Yoruba Hymn APA 178 - F’ ore-ofe Re ba wa gbe

Yoruba Hymn  APA 178 -  F’ ore-ofe Re ba wa gbe

APA 178

 1. F’ ore-ofe Re ba wa gbe,

 Jesu Olugbala;

 Ki eni arekereke,

 K’ o ma le kolu wa.


2. F’ oro mimo Re ba wa gbe,

 Jesu iyebiye;

 K’ a ri igbala on iye,

 Lohun, bi nihinyi.


3. Fi ’bukun Tire ba wa gbe,

 Oluwa Oloro;

 Fi ebun orun rere Re,

 Fun wa l’ opolopo.


4. Fi ’pamo Tire ba wa gbe,

 Iwo Alagbara:

 K’ awa k’ o le sa ota ti,

 K’ aiye k’ o ma de wa.


5. Fi otito Re ba wa gbe,

 Olorun Olore:

 Ninu ’ponju, wa ba wa re,

 Mu wa fi ori ti.


6. F’ Alafia Re ba wa gbe,

 Nigbat’ iku ba de;

 N’ iseju na, so fun wa, pe,

 Igbala nyin ti de. Amin.

Yoruba Hymn  APA 178 -  F’ ore-ofe Re ba wa gbe

This is Yoruba Anglican hymns, APA 178- F’ ore-ofe Re ba wa gbe   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post