Yoruba Hymn APA 185 - A ! Jesu, Iwo nduro

Yoruba Hymn APA 185 - A ! Jesu, Iwo nduro

Yoruba Hymn  APA 185 - A ! Jesu, Iwo nduro

APA 185

 1. A ! Jesu, Iwo nduro,

 Lode, lehin ’lekun;

 Iwo fi suru duro,

 Lati koja sile :

 ’Tiju ni fun wa, Kristian,

 Awa ti nj’ oko Re !

 Itiju gidigidi,

 B’a ba jo Re sode.


2. A ! Jesu, Iwo nkankun

 Owo na si l’ apa;

 Egun yi ori Re ka,

 Ekun b’ oju Re je:

 A ! ife ’yanu l’ eyi,

 T’o nfi suru duro !

 A ! ese ti ko l’ egbe,

 T’o ha ’lekun pinpin !


3. A ! Jesu, Iwo mbebe

 L’ ohun pelepele,

 “Mo ku f’ enyin omo mi

 Bayi l’ e se mi si ?

 Oluwa, a silekun

 N’ ikanu on ’tiju !

 Olugbala, wa wole

 Ma fi wa sile lo. Amin.

Yoruba Hymn  APA 185 - A ! Jesu, Iwo nduro

This is Yoruba Anglican hymns, APA 185 -  A ! Jesu, Iwo nduro  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post