Yoruba Hymn APA 188 - Olorun, Baba mi, ’Wo npe

Yoruba Hymn APA 188 - Olorun, Baba mi, ’Wo npe

Yoruba Hymn  APA 188 - Olorun, Baba mi, ’Wo npe

APA 188

 1. Olorun, Baba mi, ’Wo npe

 Asako omo Re mora ?

 Iwo o ha dariji mi ?

 Mo de, mo de, jo gba mi la.


2. A ! Jesu, Iwo nrekoja

 Pelu ore at’ agbara ?

 ’Wo ko ha ngbo igbe mi bi ?

 Mo de, mo de, sanu fun mi.


3. A ! Emi Mimo, Iwo ni ?

 Ore ti mo ti sati pe !

 ’Wo ha mbebe fun mi sibe ?

 Mo de, mo de, m’ ailera le.


4. Mo de, Oluwa, ife Re

 Ni o nro mi t’o si nfa mi:

 Mo wole lese Re, ki mmo

 B’o ti dun lati je Tire. Amin.

Yoruba Hymn  APA 188 - Olorun, Baba mi, ’Wo npe

This is Yoruba Anglican hymns, APA 188 -  Olorun, Baba mi, ’Wo npe. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post