Yoruba Hymn APA 199 - Ara, e wa ba mi sofo

Yoruba Hymn APA 199 - Ara, e wa ba mi sofo

 Yoruba Hymn  APA 199 - Ara, e wa ba mi sofo

APA 199

1. Ara, e wa ba mi sofo;

 E wa sodo Olugbala;

 Wa, e je k’a jumo sofo;

 A kan Jesu m’ agbelebu.


2. Ko ha s’omije loju wa,

 Bi awon Ju ti nfi sefe?

 A ! e wo, b’ O ti teriba;

 A kan Jesu m’ agbelebu.


3. Emeje l’ O soro ife;

 Idake wakati meta

 L’o fi ntoro anu f’ enia;

 A kan Jesu m’ agbelebu.


4. Bu s’ekun, okan lile mi!

 Ese at’ igberaga re

 L’o da Oluwa re l’ ebi;

 A kan Jesu m’ agbelebu.


5. Wa duro ti agbelebu,

 K’ eje tin jade niha Re

 Ba le ma san le o lori;

 A kan Jesu m’ agbelebu.


6. Ibanuje at’ omije,

 Bere, a ki o fi du o;

 ’Banuje l’o nf’ ife re han:

 A kan Jesu ‘ agbelebu.


7. Ife Baba, ese eda,

 Nihin l’a ri agbara re;

 Ife l’o si di Asegun,

 A kan Olufe wa mogi. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 199 - Ara, e wa ba mi sofo . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post