Yoruba Hymn APA 198 - E je k’a to Jesu wa lo

Yoruba Hymn APA 198 - E je k’a to Jesu wa lo

 Yoruba Hymn  APA 198 - E je k’a to Jesu wa lo

APA 198

1. E je k’a to Jesu wa lo,

 Ni agbala nla ni;

 Nibiti o nlo gbadura,

 Nibit’ o nlo kanu.


2. K’a wo b’ O ti dojubole,

 T’ o mmi imi edun;

 Eru ese wa l’ O gberu,

 Ese gbogbo aiye.


3. Elese, wo Oluwa re,

 Eni mimo julo;

 Nitori re ni Baba ko,

 Aiye si d’ ota re.


4. Iwo o ha wo laironu,

 Lai k’ ese re sile?

 Ojo idariji nkoja,

 Ojo igbala nlo. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 198- E je k’a to Jesu wa lo  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post