Yoruba Hymn APA 207 - Gbati mo ri agbelebu

Yoruba Hymn APA 207 - Gbati mo ri agbelebu

 Yoruba Hymn  APA 207 - Gbati mo ri agbelebu

APA 207

1. ’Gbati mo ri agbelebu,

 Ti a kan Oba ogo mo,

 Mo ka gbogbo oro s’ ofo,

 Mo kegan gbogbo ogo mi.


2. K’ a ma se gbo pe, mo nhale,

 B’ o ye n iku Oluwa mi;

 Gbogbo nkan asan ti mo fe.

 Mo da sile fun eje Re.


3. Wo lat’ ori, owo, ese;

 B’ ikanu at’ ife tin san;

 ’Banuje at’ ife papo,

 A f’egun se ade ogo.


4. Gbogbo aiye ba je t’ emi,

 Ebun abere ni fun mi;

 Ife nla ti nyanilenu

 Gba gbogbo okan, emi mi. Amin.


Yoruba Hymn  APA 207 - Gbati mo ri agbelebu


This is Yoruba Anglican hymns, APA 207 -  Gbati mo ri agbelebu  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post