Yoruba Hymn APA 208 - Agbelebu ni ere mi

Yoruba Hymn APA 208 - Agbelebu ni ere mi

 Yoruba Hymn  APA 208 - Agbelebu ni ere mi

APA 208

1. Agbelebu ni ere mi,

 Nibe ni a rubo fun mi;

 Nibe l’ a kan Oluwa mo,

 Nibe l’ Olugbala mi ku.


2. Kini o le fa okan Re

 Lati teri gba iya mi?

 Aimohun na daju l’ o se

 T’ okan mi tutu be si O.


3. Aifohun na oju ti mi

 Niwaju Jesu mimo mi,

 T’ o taje Re sile fun mi,

 Tori o fe mi l’ afeju. Amin.Yoruba Hymn  APA 208 - Agbelebu ni ere mi


This is Yoruba Anglican hymns, APA 208 - Agbelebu ni ere mi . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post