Yoruba Hymn APA 218 - Oro ayo na de

Yoruba Hymn APA 218 - Oro ayo na de

Yoruba Hymn  APA 218 - Oro ayo na de

APA 218

 1. Oro ayo na de,

 Olugbala bori;

 O fi boji sile

 Bi Olodumare,

 A d’ igbekun ni gbekun lo;

 Jesu t’ o ku di alaye.


2. Onigbowo wa ku

 Tani to fi wa sun?

 Baba da wa lare,

 Tal’ o to da ebi?

 A d’ igbekun, &c.


3. Kristi ti san gbese;

 Ise ogo pari;

 O ti ran wa lowo;

 O ti ba wa segun.

 A d’ igbekun, &c. Amin.Yoruba Hymn  APA 218 - Oro ayo na de

This is Yoruba Anglican hymns, APA 218-  Oro ayo na de . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post