Yoruba Hymn APA 225 - ALLELUYA! ALLELUYAH! ALLELUYAH

Yoruba Hymn APA 225 - ALLELUYA! ALLELUYAH! ALLELUYAH

Yoruba Hymn  APA 225 - ALLELUYA! ALLELUYAH! ALLELUYAH

APA 225

1. ALLELUYA! ALLELUYAH! ALLELUYAH!

 Ija d’ opin, ogun si tan:

 Olugbala jagun molu;

 Orin ayo l’ a o ma ko.—Alleluya!


2. Gbogbo ipa n’ iku ti lo;

 Sugbon Kristi f’ ogun re ka:

 Aiye! e ho iho ayo. –Alleluyah.


3. Ojo meta na ti koja,

 O jinde kuro nin’ oku:

 E f’ ogo fun Oluwa wa. – Alleluya.


4. O d’ ewon orun apadi,

 O silekun orun sile;

 E korin iyin segun Re. –Alleluyah.


5. Jesu, nipa iya t’ O je,

 Gba wa lowo oro iku,

 K’a le ye, k’a si ma yin O. –Alleluya. Amin. 


Yoruba Hymn  APA 225 - ALLELUYA! ALLELUYAH! ALLELUYAH


This is Yoruba Anglican hymns, APA 225-   ALLELUYA! ALLELUYAH! ALLELUYAH   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post