Yoruba Hymn APA 287 - Olorun Olodumare

Yoruba Hymn APA 287 - Olorun Olodumare

Yoruba Hymn  APA 287 - Olorun Olodumare

APA 287

 1. Olorun Olodumare,

 Baba, Omo, Emi,

 Riri enit’ a ko le mo,

 Enit’ a ko le ri.

 

2. Ye! Baba Olodumare,

 K’ a wariri fun O;

 Ni gbogbo orile ede,

 Li a o ma sin O.


3. Olorun Omo, Ore wa,

 ’Wo t’ o raw a pada,

 Ma jowo wa, Olugbala!

 Gba wa patapata.


4. A! Olorun Emi Mimo,

 ’Wo olore-ofe;

 A be O, fun wa ni imo,

 K’ a m’ Olorun n’ ife.


5. Okansoso sugbon meta,

 Eni Metalokan,

 Olorun awamaridi,

 Eni Metalokan! Amin.Yoruba Hymn  APA 287 - Olorun Olodumare

This is Yoruba Anglican hymns, APA 287- Mimo, mimo, mimo! Olodumare   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post