Yoruba Hymn APA 293 - Olorun l’ abo eni Re

Yoruba Hymn APA 293 - Olorun l’ abo eni Re

Yoruba Hymn  APA 293 - Olorun l’ abo eni Re

APA 293

 1. Olorun l’ abo eni Re,

 Nigba iji iponju de;

 K’ awa to se aroye wa,

 A! saw o t’ on t’ iranwo Re.


2. B’ agbami riru mbu soke,

 Okan w mbe l’ alafia;

 Nigb’ orile at’ etido,

 Ba njaya riru omi na.


3. Iwe owo ni oro Re,

 Kawo ibinu fufu wa;

 Oro Re m’ alafia wa,

 O f’ ilera f’ okan are. Amin.Yoruba Hymn  APA 293 - Olorun l’ abo eni Re

This is Yoruba Anglican hymns, APA 29- Olorun l’ abo eni Re . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post