Yoruba Hymn APA 316 - Isun kan wa t’ o kun f’ eje

Yoruba Hymn APA 316 - Isun kan wa t’ o kun f’ eje

Yoruba Hymn  APA 316 - Isun kan wa t’ o kun f’ eje

APA 316

 1. Isun kan wa t’ o kun f’ eje,

 To ti ‘ha Jesu yo;

 Elese mokun ninu re,

 O bo ninu ebi.


2. ‘Gba mo f’ igbagbo r’ isun na,

 Ti nsan fun eje Re,

 Irapada d’ orin fun mi,

 Ti ngo ma ko titi.


3. Orin t’o dun ju eyi lo,

 Li emi o ma ko:

 ‘Gbat’ akololo ahon yi

 Ba dake ni ibojui.


4. Mo gbagbo p’ O pese fun mi

 (Bi mo tile s’a aiye),

 Ebun ofe t’ a f’ eje ra,

 Ati duru wura.


5. Duru t’ a tow’ Olorun se,

 Ti ko ni baje lai;

 Ti ao ma fi yin Baba wa,

 Oruko Re nikan. Amin.Yoruba Hymn  APA 316 - Isun kan wa t’ o kun f’ eje

This is Yoruba Anglican hymns, APA 316-  Isun kan wa t’ o kun f’ eje  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post