Yoruba Hymn APA 317 - Ohun ogo Re l’ a nrohin

Yoruba Hymn APA 317 - Ohun ogo Re l’ a nrohin

Yoruba Hymn  APA 317 - Ohun ogo Re l’ a nrohin

APA 317

 1. Ohun ogo Re l’ a nrohin,

 Sion, ti Olorun wa:

 Oro enit’ a ko le ye,

 Se o ye fun bugbe Re.

 L’ori apat’ aiyeraiye,

 Kini le mi ’simi re?

 A f’ odi ’gbala yi o ka,

 K’ o le ma rin ota re.


2. Wo! ipado omi iye,

 Nt’ ife Olorun sun wa,

 O to fun gbogbo omo Re,

 Eru aini ko si mo;

 Tal’ o le re, ’gba odo na

 Ban san t’ o le pongbe re?

 Or’-ofe Olodumare

 Ki ye lat’ irandiran.


3. Ara Sion alabukun,

 T’ a f’ eje Oluwa we;

 Jesu ti nwon ti ngbekele,

 So won d’ oba, woli Re.

 Sisa l’ ohun afe aiye,

 Pelu ogo asan re,

 Isura toto at’ ayo,

 Kik’ omo Sion l’ o mo. Amin.



Yoruba Hymn  APA 317 - Ohun ogo Re l’ a nrohin

This is Yoruba Anglican hymns, APA 317-Ohun ogo Re l’ a nrohin   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post