Yoruba Hymn APA 320 - Gba mo le ka oye mi re

Yoruba Hymn APA 320 - Gba mo le ka oye mi re

 Yoruba Hymn  APA 320 - Gba mo le ka oye mi re

APA 320

1. ’Gba mo le ka oye mi re,

 Ni ibugbe l’ oke;

 Mo dagbere f’ eru gbogbo,

 Mo n’ omije mi nu.


2. B’ aiye kojuja s’ okan mi,

 T’ a nso oko si i;

 ’Gbana mo le rin Satani,

 Ki nsi jeju k’ aiye.


3. K’ aniyan de b’ ikun omi,

 K’ iji banuje ja;

 Ki nsa de ’le Alafia,

 Olorun, gbogbo mi.


4. Nibe l’ okan mi y’o luwe,

 N’nu okun isimi;

 Ko si wahala t’ o le de,

 S’ ibale aiya mi. Amin.Yoruba Hymn  APA 320 - Gba mo le ka oye mi re

This is Yoruba Anglican hymns, APA 320-  Gba mo le ka oye mi re  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post