Yoruba Hymn APA 321 - Nipa Ife Olugbala

Yoruba Hymn APA 321 - Nipa Ife Olugbala

 Yoruba Hymn  APA 321 - Nipa Ife Olugbala

APA 321

1. Nipa Ife Olugbala,

 Ki y’ o si nkan;

 Ojurere Re ki pada,

 Ki y’o si nkan.

 Owon l’eje t’ o wo wa san;

 Pipe l’ edidi or’ ofe;

 Agbara l’owo t’o gba ni;

 Ko le si nkan.


2. Bi a wa ninu iponju,

 Ki y’o si nkan;

 Igbala kikun ni tiwa,

 Ki y’ o si nkan;

 Igbekele Olorun dun;

 Gbigbe inu Kristi l’ ere;

 Emi si nso wa di mimo;

 Ko le si nkan.


3. Ojo ola yio dara,

 Ki y’ o si nkan.

 ‘Gbagbo le korin n’ iponju,

 Ki y’o si nkan.

 A gbekele ‘fe Baba wa;

 Jesu nfun wa l’ ohun gbogbo;

 Ni yiye tabi ni kiku,

 Ko le si nkan. Amin.Yoruba Hymn  APA 321 - Nipa Ife Olugbala

This is Yoruba Anglican hymns, APA 321-  Nipa Ife Olugbala   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post