Yoruba Hymn APA 328 - A ba le n’igbagbo aye

Yoruba Hymn APA 328 - A ba le n’igbagbo aye

Yoruba Hymn  APA 328 -  A ba le n’igbagbo aye

APA 328

 1. A ba le n’igbagbo aye,

 B’o ti wu k’ota po;

 Igbagbo ti ko je mira

 Tun aini at’ osi.


2. Igbagbo ti ko je rahun

 L’abe ibawi Re;

 Sugbon ti nsmi l’Olorun,

 Nigba ibanuje.


3. Igbagbo ti ntan siwaju,

 Gbat’ iji ‘ponju de;

 Ti ko si je siyemeji,

 N’nu wahala gbaogbo.


4. Igbagbo ti ngb’ona toro,

 Titi emi o pin;

 Ti y’o si f’imole orun,

 Tan akete iku.


5. Jesu f’ igbagbo yi fun mi:

 Nje, b’o ti wu k’o ri,

 Lat’ aiye yi lo ngo l’ayo

 Ilu orun rere. Amin.Yoruba Hymn  APA 328 -  A ba le n’igbagbo aye

This is Yoruba Anglican hymns, APA 328- A ba le n’igbagbo aye    . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post