Yoruba Hymn APA 327 - Igbagbo mi duro, l’ori

Yoruba Hymn APA 327 - Igbagbo mi duro, l’ori

Yoruba Hymn  APA 327  - Igbagbo mi duro, l’ori

APA 327

 1. Igbagbo mi duro, l’ori

 Eje at’ ododo Jesu;

 Nko je gbekele ohun kan,

 Lehin oruko nla Jesu:

 Mo duro le Krisit’ Apata,

 Ile miran, iyanrin ni.


2. B’ ire-ije mi tile gun,

 Or’ – ofe Re ko yipada;

 B’ o ti wu k’iji na le to,

 Idakoro mi ko ni ye:

 Mo duro le Krist’ Apata,

 Ile miran, iyanrin ni.


3. Majemu ati eje Re,

 L’ em’ o romo b’ ikunmi de

 Gbati ko s’atilehin mo,

 O je ireti nla fun mi:

 Mo duro le Kristi’ Apata

 Ile miran, iyanrin ni.


4. Gbat’ ipe kehin ba si dun,

 A! mba le wa ninu Jesu,

 Ki nwo ododo Re nikan,

 Ki nduro niwaju ite:

 Mo duro le Krist’ Apata,

 Ile miran, iyanrin ni. Amin.Yoruba Hymn  APA 327  - Igbagbo mi duro, l’ori

This is Yoruba Anglican hymns, APA 327-  Gba mo le ka oye mi re  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post