Yoruba Hymn APA 330 - Jesu, kiki ironu Re

Yoruba Hymn APA 330 - Jesu, kiki ironu Re

Yoruba Hymn  APA 330 - Jesu, kiki ironu Re

APA 330

 1. Jesu, kiki ironu Re,

 Fi ayo kun okan;

 Sugbon k’a ri O l’o dun ju,

 K’a simi lodo Re.


2. Enu ko so, eti ko gbo,

 Ko ti okan wa ri;

 Oko t’o sowon, t’o dun bi

 Ti Jesu Oluwa.


3. Ireti okan ti nkanu,

 Olore elese;

 O seun f’ awon ti nwa O,

 Awon t’o ri O yo.


4. Ayo won, enu ko le so,

 Eda ko le rohin;

 Ife Jesu, b’o tip o to,

 Awon Tire l’o mo.


5. Jesu, ’Wo ma je ayo wa,

 ’Wo sa ni ere wa;

 Ma je ogo wa nisiyi,

 Ati titi lailai. Amin.Yoruba Hymn  APA 330 - Jesu, kiki ironu Re

This is Yoruba Anglican hymns, APA 330-  Jesu, kiki ironu Re  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post