Yoruba Hymn APA 331 - B’ oruko Jesu ti dun to

Yoruba Hymn APA 331 - B’ oruko Jesu ti dun to

Yoruba Hymn  APA 331 - B’ oruko Jesu ti dun to

APA 331

 1. B’ oruko Jesu ti dun to

 Leti olugbagbo!

 O tan banuje on ogbe,

 O le eru re lo.


2. O wo okan t’o gbogbe san,

 O mu aiya bale;

 Manna ni fun okan ebi,

 Isimi f’ alare.


3. Apata ti mo kole le,

 Ibi isadi mi:

 Ile isura mi t’o kun,

 F’opo ore-ofe.


4. Jesu, Oko mi, Ore mi,

 Woli mi, Oba mi:

 Alufa mi, Ona, Iye,

 Gba orin iyin mi.


5. Ailera l’agbara ‘nu mi,

 Tutu si l’ero mi:

 ‘gba mo ba ri O b’ O ti ri,

 Ngo yin O b’o ti ye.


6. Tit’ igbana ni ohun mi,

 Y’o ma rohin ‘fe Re;

 Nigba iku, k’ Oruko Re;

 F’ itura f’ okan mi. Amin.Yoruba Hymn  APA 331 - B’ oruko Jesu ti dun to

This is Yoruba Anglican hymns, APA 331- B’ oruko Jesu ti dun to   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post