Yoruba Hymn APA 336 - Gbat aiye yi ba koja

Yoruba Hymn APA 336 - Gbat aiye yi ba koja

Yoruba Hymn  APA 336 - Gbat aiye yi ba koja

APA 336

 1. ’Gbat aiye yi ba koja,

 Ti orun re ba si wo,

 Ti a ba wo ’nu ogo,

 T’ a bojuwo ehin wa;

 ’Gbana, Oluwa, ngo mo

 Bi gbese mi tip o to.


2. ’Gba mo ba de ’b’ ite Re,

 L’ ewa ti ki se t’emi;

 ’Gba mo ri O b’ o ti ri,

 Ti mo fe O l’ afetan;

 ’Gbana Oluwa, ngo mo

 Bi gbese mi ti po to.


3. ’Gba mba ngbo orin orun,

 Ti ndun bi ohun ara,

 Bi iro omi pupo:

 T’ o si ndun b’ ohun duru;

 ’Gbana Oluwa, ngo mo

 Bi gbese mi ti po to.


4. Oluwa, jo, je k’a ri

 Ojiji Re l’ aiye yi;

 K’ a mo adun dariji,

 Pelu iranwo Emi;

 Kin tile mo l’ aiye yi,

 Die ninu gbese mi.


5. Ore-ofe l’ o yan mi,

 L’ o yo mi ninu ewu;

 Jesu l’ Olugbala mi,

 Emi so mi di mimo,

 Ko mi ki nfi han l’aiye,

 Bi gbese mi ti po to.! Amin.Yoruba Hymn  APA 336 - Gbat aiye yi ba koja

This is Yoruba Anglican hymns, APA 336- Gbat aiye yi ba koja   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post