Yoruba Hymn APA 337 - Awa ko orin ife Re

Yoruba Hymn APA 337 - Awa ko orin ife Re

 Yoruba Hymn  APA 337 - Awa ko orin ife Re

APA 337

1. Awa ko orin ife Re,

 Obangiji Oba Ogo;

 Ko s’ ohun ti lalasi Re,

 Ola Re ko si nipekun.


2. N’nu ife l’o s’ eda aiye,

 O da enia sinu re;

 Lati ma s’ akoso gbogbo;

 E korin ’fe Eleda wa.


3. Lojojumo l’ O ntoju wa,

 O si mbo, O si nsike wa;

 Beni ko gba nkan lowo wa,

 Korin ’yin s’ onibu ore.


4. O ri wa ninu okunkun,

 Pe, a ko mo ojubo re;

 N’ ife O fi ona han wa;

 E korin ife Olore!


5. N’ ife O fi Jesu fun wa,

 Omobibi Re kansoso;

 O war a wa lowo ese;

 A yin ’fe Re Olugbala!


6. Ife Re ran oro Re wa,

 Ife Re l’ o si wa leti,

 Ife Re si mu wa duro;

 E korin ore-ofe Re.


7. Gbogbo eda kun fun ’fe Re,

 Oluwa wa, Oba aiye;

 Gbogbo agbaiye, e gberin,

 Orin ife Olorun wa. Amin.Yoruba Hymn  APA 337 - Awa ko orin ife Re

This is Yoruba Anglican hymns, APA 337-  Awa ko orin ife Re   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post