Yoruba Hymn APA 342 - O fun mi l’ edidi

Yoruba Hymn APA 342 - O fun mi l’ edidi

Yoruba Hymn  APA 342 - O fun mi l’ edidi

APA 342

 1. O fun mi l’ edidi,

 ’Gbese nla ti mo je;

 B’o ti fun mi, O si rerin

 Pe, “Mase gbagbe mi!”


2. O fun mi l’ edidi,

 O san igbese na;

 B’o ti fun mi, O si rerin

 Wipe, “Ma ranti mi!”


3. Ngo p’ edidi na mo,

 B’ igbese tile tan;

 O nso ife enit’ o san

 Igbese na fun mi.


4. Mo wo, mo si rerin;

 Mo tun wo, mo sokun;

 Eri ife Re si mi ni,

 Ngo toju re titi.


5. Kit un s’ edidi mo,

 Sugbon iranti ni!

 Pe gbogbo igbese mi, ni

 Emmanueli san. Amin.Yoruba Hymn  APA 342 - O fun mi l’ edidi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 342-  O fun mi l’ edidi. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post