Yoruba Hymn APA 343 - Fe enikeji re

Yoruba Hymn APA 343 - Fe enikeji re

 Yoruba Hymn  APA 343 - Fe enikeji re

APA 343

1. “Fe enikeji re,”

 Ase Oluwa ni;

 O sa f’ ara Re s’ apere,

 Ni fife t’ O fe wa.


2. “Fe enikeji re,”

 N’ ire tabi n’ ija;

 O ko w ape k’a f’ ota wa,

 K’a f’ ore san ibi.


3. “Fe enikeji re,”

 Oluwa nke tantan;

 O ye ki gbogbo wa mura,

 K’a f’ ore san ibi.


4. Fe enikeji re,

 At’ aladugbo re,

 Pelu gbogb’ eni yi o ka,

 At’ ota re pelu.


5. K’ a f’ enikeji wa,

 Bi Jesu ti fe wa,

 Jesus a f’ awon ota Re,

 O si sure fun won. Amin.



Yoruba Hymn  APA 343 - Fe enikeji re

This is Yoruba Anglican hymns, APA 343-  Fe enikeji re  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post