Yoruba Hymn APA 344 - Jesu, Iwo ni a nwo

Yoruba Hymn APA 344 - Jesu, Iwo ni a nwo

Yoruba Hymn  APA 344 - Jesu, Iwo ni a nwo

APA 344

 1. Jesu, Iwo ni a nwo,

 K’ a repo l’ oruko Re;

 Alade Alafia,

 Mu k’ ija tan l’ arin wa.

 

2. Nipa ilaja Tire,

 Mu idugbolu kuro:

 Je k’ a dapo si okan;

 F’ itegun Re sarin wa.


3. Je k’ a wa ni okan kan,

 K’ a se anu at’ ore;

 K’ a tutu l’ ero, l’okan,

 Gege bi Oluwa wa.


4. K’ a s’ aniyan ara wa,

 K’ a ma reru ara wa,

 K’ a f’ apere fun Ijo,

 B’ olugbagbo ti gbe po.


5. K’ a kuro ni ibinu,

 K’ a simi le Olorun;

 K’ a so ti ibu ife,

 At’ iwa giga mimo.


6. K’ a f’ ayo kuro laiye,

 Lo si Ijo ti orun;

 K’ a f’ iye Angeli fo,

 K’ a le ku b’ eni mimo. Amin.Yoruba Hymn  APA 344 - Jesu, Iwo ni a nwo

This is Yoruba Anglican hymns, APA 344- Jesu, Iwo ni a nwo  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post