Yoruba Hymn APA 361 - Jesu, ma to wa

Yoruba Hymn APA 361 - Jesu, ma to wa

Yoruba Hymn  APA 361 - Jesu, ma to wa

APA 361

 1. Jesu, ma to wa,

 Tit’ ao fi simi;

 Bi ona wa ko tile dan,

 A o tele O l’ aifoiya:

 F’ owo Re to wa

 S’ ilu Baba wa.


2. B’ ona ba lewu,

 B’ ota sunmo wa,

 Ma je k’ aigbagbo m’eru wa,

 Ki gbagbo on ’reti ma ye;

 Tor’ arin ota

 L’a nlo s’ ile wa.


3. Gbat’ a fe ’tunu

 Ninu ’banuje,

 Gbat’ idanwo titun ba de,

 Oluwa fun wa ni suru;

 F’ ilu ni han wa

 Ti ekun ko si.


4. Jesu, ma to wa,

 Tit’ ao fi simi:

 Amona orun, toju wa,

 Dabobo wa, tu wa ninu,

 Titi ao fi de

 Ilu Baba wa. Amin.Yoruba Hymn  APA 361 - Jesu, ma to wa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 361- Jesu, ma to wa   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post