Yoruba Hymn APA 360 - Ma toju wa Baba orun

Yoruba Hymn APA 360 - Ma toju wa Baba orun

 Yoruba Hymn  APA 360 - Ma toju wa Baba orun

APA 360

1. Ma toju wa Baba orun,

 Larin ’damu aiye yi;

 Pa wa mo k’ o si ma bo wa,

 A ko n’ iranwo miran;

 Sugbon gbogbo ’bukun l’ a ni,

 B’ Olorun je Baba wa.


2. Olugbala, dariji wa,

 Iwo sa m’ ailera wa:

 ’Wo ti rin aiye saju wa,

 ’Wo ti mo ’se inu re;

 B’ en’ ikanu at’ alare,

 L’ O ti la ’ginju yi ja.


3. Emi Olorun, sokale,

 F’ ayo orun k’ okan wa;

 K’ ife dapo mo iya wa,

 At’ adun ti ki su ni;

 B’ a ba pese fun wa bayi,

 Ki l’ o le mi ’simi wa? Amin. Yoruba Hymn  APA 360 - Ma toju wa Baba orun

This is Yoruba Anglican hymns, APA 360- Ma toju wa Baba orun  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post