Yoruba Hymn APA 407 - Emi okan wa npe

Yoruba Hymn APA 407 - Emi okan wa npe

 Yoruba Hymn  APA 407 - Emi okan wa npe

APA 407

1. Emi okan wa npe,

 O np’elese k’o wa;

 ’Yawo, Ijo Kristi si npe,

 K’ awon omo re wa.


2. Je k’ eni t’ o gbo, wi

 F’ awon t’ o yika, wa;

 Enit’ ongbe ododo ngbe,

 K’ o wa sodo Kristi.


3. Loto, eni t’ o fe,

 Je ki o wa l’ ofe;

 K’ o mu omi iye l’ ofe,

 Jesu l’ o pe k’ o wa.


4. Gbo bi Jesu ti npe,

 Wipe, mo mbo Kankan;

 Beni, Jesu mo nreti Re,

 Ma bo Olugbala. Amin.



Yoruba Hymn  APA 407 - Emi okan wa npe

This is Yoruba Anglican hymns, APA 407- Emi okan wa npe . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post