Yoruba Hymn APA 440 - Wo Oba anu, lat’ or’ ite Re

Yoruba Hymn APA 440 - Wo Oba anu, lat’ or’ ite Re

 Yoruba Hymn  APA 440 - Wo Oba anu, lat’ or’ ite Re

APA 440

1. ‘Wo Oba anu, lat’ or’ ite Re,

 Fi ife wow a, si gbo igbe wa.


2. ‘Wo Olusagutan enia Re,

 Pa awon abgo agutan Re mo.


3. Olugbala, iku Re n’iye wa,

 F’iye anipekun fun gbogbo wa.


4. Onje orun, Iwo ni onje wa,

 Se ‘ranwo okan wa nigba ‘ponju.


5. ‘Wo l’Alabaro, Ore elese,

 ‘Wo n’ Ibu ayo wa titi lailai.


6. Wa f’ore- ofe Re mu ‘nu wa dun,

 Si je k’a ma ri ojurere Re.


7. Nigba osan, ati nigba oru,

 Sunmo wa, k’o s’okun wa d’ imole.


8. Ma ba wa lo, k’o si ma ba wag be,

 N’iye, n’iku, ma je itunu wa.


9. L’ojojumo f’oju ‘fe Re to wa, 

Si mu wa de ‘le wa l’alafia. Amin.Yoruba Hymn  APA 440 - Wo Oba anu, lat’ or’ ite Re

This is Yoruba Anglican hymns, APA 440- Wo Oba anu, lat’ or’ ite Re. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post