Yoruba Hymn APA 448 - Nihinyi n’ isimi gbe wa

Yoruba Hymn APA 448 - Nihinyi n’ isimi gbe wa

Yoruba Hymn  APA 448 - Nihinyi n’ isimi gbe wa

APA 448

1. Nihinyi n’ isimi gbe wa,

 Niha re t’ eje nsan;

 Eyi nikan n’ ireti mi,

 Pe Jesu ku fun mi.


2. Olugbala, Olorun mi,

 Orisun f’ ese mi;

 Ma f’ eje Re won mi titi,

 K’ emi le di mimo.


3. We mi, si se mi ni Tire,

 We mi, si je temi;

 We mi, k’ is’ ese mi nikan,

 Owo at’ okan mi.


4. Ma sise l’ okan mi, Jesu,

 Titi ’gbagbo y’o pin;

 Tit’ ireti y’o fi dopin,

 T’ okan mi y’o simi. Amin.Yoruba Hymn  APA 448 - Nihinyi n’ isimi gbe wa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 448- Nihinyi n’ isimi gbe wa. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals


Post a Comment (0)
Previous Post Next Post