Yoruba Hymn APA 463 - Jesu onirele

Yoruba Hymn APA 463 - Jesu onirele

Yoruba Hymn  APA 463 - Jesu onirele

APA 463

 1. Jesu onirele,

 Omo Olorun:

 Alanu, olufe,

 Gbo ’gbe omo Re.


2. Fi ese wa ji wa,

 Si da wa n’ ide;

 Fo gbogbo orisa

 Ti mbe l’ okan wa.


3. Fun wa ni ominira,

 F’ ife s’ okan wa;

 Fa wa Jesu mimo,

 S’ ibugbe l’ oke.


4. To wa l’ ona ajo,

 Si je ona wa

 La okun aiye ja

 S’ imole orun.


5. Jesu onirele,

 Omo Olorun;

 Alanu, Olufe,

 Gbo ’gbe omo Re. Amin.Yoruba Hymn  APA 463 - Jesu onirele

This is Yoruba Anglican hymns, APA 463- Jesu onirele . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post